Abstract

In the song and music video “Lùlù fún wọn” (Drum for them), Ìjálá artist Kojo Àyánwọlá praises Lágbájá, whose name means “somebody, anybody, nobody.” It is a peculiar challenge for a poet to sing praises for such a person. Yorùbá praise poetry, known as oríkì, canonically identifies one’s place of origin, family heritage, and good deeds. According to Lágbájá’s oríkì, his mother is the one who sells cowskin, which could be just about anyone. Lágbájá’s music video celebrates oríkì while pointing out its incongruity with contemporary urban life, in which heritage and culture are obscured by the quotidian. This article presents a survey of recent performances and recordings that alternately adapt or juxtapose the oríkì tradition to life in contemporary Nigeria.

Ní àkékúrú, nínú orin “Lùlù fún wọn”, Asùn’jálá Kojo Àyànwolé korin ki Lágbájá. Òrò yí, Lágbájá túmò sí “enikan, enikéni, enìkan ò sí. Ó jé ohun tó le ní pàtàkì jù lo láti korin oríkì irú okùnrin béè. Ásà oríkì tí ó jé ti Yorùbá kanlè to pinpin ibi tí a gbé sàn wa, àwon isé ìdílé eni àti ìwà ohun rere tí a gbé se. Gégé bí oríkì Lágbájá, ìyá rè jé eni tí ó nta pònmó, èyí já sí pé ó lè jé enikéni. Àwòrán orin Lágbájá gbé oríkì l’áruge nígbà tí ó sì tún fi títako ìgbé ayé ìgbàlódé àárín ìgboro, níbi tí ìgbé ayé ìdèra ojojúmó ti bo àsà àti ìse ìbílè lójú. Ìwé yí se àgbéyèwò àwon eré àti ìgbàsílè sínú èro tí ó se àyálò tàbí àfiwé àsà oríkì pèlú ìgbé ayé òde òní ní Ilè Nigeria (Nàìjíríà).

The text of this article is only available as a PDF.
You do not currently have access to this content.